Добавил:
Upload Опубликованный материал нарушает ваши авторские права? Сообщите нам.
Вуз: Предмет: Файл:

YorubaPrimer

.pdf
Скачиваний:
6
Добавлен:
12.02.2015
Размер:
4.28 Mб
Скачать

Köþsónàýtì YORÙBÀ Consonants

Àwôn Köþsónàýtì Yorùbá

Yoruba Consonants

B

J

R

b

j

r

D

K

S

d

k

s

F

L

ß

f

l

ÿ

G

M

T

g

GB gb

H

m

N n

P

t

W w

Y

h

p

y

Àwôn lëtà tí ó máa þsábà

The letters that are usually

ÿòro pe fún àwôn tí kìí

difficult for non-native Yoruba

ÿe ômô ìbílê Yorùbá ni-

speakers to pronounce are -

 

GB gb

àti

P p

 

 

 

and

 

 

 

 

fún àpççrç

 

for

example

gbà

gbà

to take

pa

pa

to kill

gbé

gbé

to carry

to call

gbç

gbç

dry

late

gbö

gbö

to hear

papa

pápá

field

gbàgbé

gbàgbé

to forget

pçpç

pçpç

altar

gbogbo

gbogbo

all

pupa

pupa

red

gbígbç

gbígbç

dry

púpõ

many

 

Dán wôn wò

 

Try them

 

Page 5

 

 

 

 

Ojú-ìwé Karùn-ún

Fonölöjì Yorùbá Phonology

Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá.

The tone is the pillar of the Yoruba language.

Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá. Ìró ohùn èdè ni à þ pé ni Fonölöjì. Ìró ohùn ìpilê mëta ni ó wà ní èdè Yorùbá. Àwôn ni ohùn òkè, àárín àti ìsàlê.

The tone is the pillar of the Yoruba language. Phonology is the speech sounds of a language. There are three basic tones in Yoruba. They are the high, middle and low tones.

A fi àwôn àmì ohùn mëta yìí töka sí wôn.

Àmì ohùn ìsàlê Àmì ohùn òkè Àmì ohùn àárín

These three accent marks are used to indicate them.

( ` ) Grave sign ( ´ ) Acute sign

( ¯ ) Mid tone sign

Àkíyèsí

A kì í sábà fi àmì sí orí õrõ olóhùn àárín àfi lëêkõõkan nígbà tí ó bá yç.

Note

We do not usually place accent marks on words with a mid tone except in some instances when necessary.

Page 6

Ojú-ìwé Kçfà

(ÈBA) ®

Fonölöjì Yorùbá Phonology

P

Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá.

The tone is the pillar of the Yoruba language.

A fi oríÿìí àwõ mëta ya àwôn àmì ohùn õrõ yìí sötõ kí ó lè rôrùn fún àwôn ômôdé àti alákõöbërê láti ÿe àkíyèsí wôn. Ètò

tí a dá sílê yìí ni a pè ní Ètò Bis Bus Afàwõ-ÿe-ìlànà.

We assigned three different colors to distinguish between these three tones to make it easy for children and beginners alike to notice them. We devised this technique and called it the Bis Bus Color Coding Scheme (BCS) ®

( ˋ )

àwõ aró

blue

re

( )

( ˉ ) àwõ ewé

green

( ˊ )

àwõ pupa

red

Page 7

Ojú-ìwé Keje

Fonölöjì Yorùbá Phonology

P

Ìró ohùn

Phonology

Mëta nínú àwôn ohùn orin tí a þ tê lórí dùrù ni a fi þ töka sí dídún ohùn õrõ.

Àwôn olùkö àti akëkõö èdè Yorùbá ti lo àýfàní yìí fún õpõlôpõ ôdún.

Three of the musical notes of the piano are used to simulate the intonation of words. This has been used with good effect by Yoruba teachers and students for many years.

d:

r:

m:

 

 

 

( ˋ

)

 

 

 

 

re

(

)

( ˉ )

 

 

 

( ˊ )

 

 

 

 

Àpççrç

 

 

 

 

Example

o(re-)

 

money

òwò (-)

trade

ô(re-)

hand

õwõ

(-)

reverence

õ(-)

flock

ô

(re-)

broom

Õwõ (-)

a town in Yoruba land

 

Àkíyèsí.

Lílo ‘do-re-mi’ kì í ÿiÿë ní àÿepé ní ìgbà gbogbo ÿùgbön ó wúlò púpõ fún alákõöbêrê.

Note.

Utilizing ‘do-re-mi’ does not work perfectly all the time, but it is very useful for the beginner.

Page 8

Ojú-ìwé Kçjô

Fonölöjì Yorùbá Phonology

P

Ìró ohùn

 

Phonology

À þ bá àwôn àmì ohùn mìíràn pàdé nínú àwôn ìwé Yorùbá àtijö àti ti òde òní.

Àwôn tí ó ÿe gógó ni:

1. Àmì fàágùn ( ~ )

A kìí lo àmì yìí mö nítorí pé kò wúlò. A ti fi lílo fàwêlì méjì tí õkõõkan ní àmì tirê dípò irú àwôn õrõ bëê. Fún àpççrç:

We do come across other intonation marks in both old and modern day Yoruba books.

The main ones are:

1. The tilde ( ~ )

This sign is no longer in use because it is not useful. The use of two vowels, each with its own intonation mark is now used in such instances. e.g.:

õrùn

lè jë

oòrùn

o-ò-rùn

sun

 

 

can be

tàbí / or

 

 

òórùn

ò-ó-rùn

smell

 

 

2. Àmì ohùn ìsàlê àti òkè àpapõ ( ˇ )

Lílo àmì yìí kò wöpõ mö nínú àwon ìwé Yorùbá. Ó dá mi lójú pé yóò ya àwôn òýkàwé wa lënu láti rí àmì tí ó ÿe àjèjì yìí lórí orúkô mi -

2. The low-rising tone ( ˇ )

This intonation mark is no longer in common use in Yoruba texts. I am sure it will come as a surprise for readers of this book to see this unfamiliar accent mark on my name –

Ônäbàjò, Ônäyçmí

A ÿe èyìí láti mú un rôrùn fún pipe orúkô náà bí ó ti tö báyìí

Ônàábàjò, Ônàáyçmí

Ogunlögõ ènìyàn ni o máa þ ÿi orúkô náà pè báyìí

Õnábàjò, Õnáyçmí

Nípa lílo àmì yìì, a yçra fún lílo fáwêlì méjì fún orúkô náà.

A tún lo àmì ohùn yìí nínú ìwé yìí fún nö¹bà 1

Kïnní dípò

Page 9

This is done to facilitate proper pronunciation of the name as

-re---, re--re-

Many people mistakenly pronounce the name like this

---- , --re-

In using this sign, doubling the vowel for the name is avoided.

This accent mark is also used in this book for the number 1

/ instead of Kìn-ìn-ní

Ojú-ìwé Kçsàn-án

Môfölöjì Yorùbá Morphology

Môfölöjì Yorùbá

Yoruba Morphology

Ètò õrõ ni a þ pè ní Môfölöjì. Ó ÿe pàtàkì láti ní ìmõ tí ó péye nípa ètò gígé çyô õrõ sí êbù-êbù (sílébù) ní èdè Yorùbá nítorí pé çyô sílébù kõõkan ni ó ní ìró ohùn tirê.

Morphology is the structure of words. It is important to have a good knowledge of how a word is divided into its component parts (syllable) in Yoruba because each syllable has its own distinct pitch.

Bátànì sílébù ìpilê mëta ni a fi þ

Three basic syllable patterns are used

hun õrõ Yorùbá.

in forming Yoruba words.

Àwôn ni:

They are:

1.

( F ) Fáwêlì

( V ) Vowel

2.

( KF ) Köþþsónáýtì + Fáwêlì (CV) Consonant + Vowel

3.

(M m, N n)

Sílébù Àránmúpè Syllabic Nasal

F

Fáwêlì

 

V

Vowel

K

Könþsónáýtì

 

C

Consonant

 

 

 

 

 

Page 10

Ojú-ìwé Kçwàá

Môfölöjì Yorùbá Morphology

Môfölöjì Yorùbá

Yoruba Morphology

Àwôn oríÿìí bátànì mëta tí ó þ wáyé nígbà tí a bá pín õrõ sí êbù-êbù sílébù nìyìí -

These are the three different patterns that occur when words are split into their component syllables -

1. ( F ) Fáwêlì ( V ) Vowel

Fáwêlì kan dá dúró gëgë bíi sílébù odidi kan

A stand-alone vowel as one complete syllable

Àpççrç / Example: a, ç, ó

aa ti dé We have arrived

çç ti dé You have arrived

óó ti dé He / She has arrived

2. ( KF ) Köþþsónáýtì + Fáwêlì (CV) Consonant + Vowel

Köþsónáýtì àti fáwêlì àpapõ gëgë bíi sílébù kan

A consonant and vowel combination as a syllable

Àpççrç / Example: bê, lù, wá, lô

Mo ö

I beg you

Don’t beat me

Jõö síbí

Please come here

Mò þ

I am going

3.M m, N n

gëgë bíi sílébù kan tí kì í ÿe ara fáwêlì àránmúpè. as a syllable that is not part of a nasalized vowel

Abimbölá

I am born into honour (AYoruba name)

þ

I am going

Ajá Adé þ gbó

-

Ade’s dog is barking

Ògòýgò, ôba çyç

-

The Ostrich, king of birds

Page 11

Ojú-ìwé Kôkànlá

 

Môfölöjì Yorùbá Morphology

Môfölöjì (Ètò õrõ) Yorùbá

Yoruba Morphology

Ó wúlò láti yára ÿe àkíyèsí bí hìhun õrõ pêlú sílébù ÿe þÿisë nípa wíwo àwôn õrõ onísílébù méjì. A óò rí bátànì méjì-

It is instructive to quickly note how these syllable building blocks work by illustrating with some bisyllabic words. Two patterns emerge

1. F – KF V - CV

2. KF –KF CV-CV

1. (F - KF) (V - CV)

Fáwêlì tí ó dá dúró àti könþsónáýtì pêlú fáwëlì àpapõ A stand-alone vowel and a consonant-vowel combination

 

 

A-

Adé

Crown

 

 

Ô-

Ôlá

Honor

2.

(KF - KF)

(CV - CV)

 

Köþsónáýtì àti fáwêlì àpapõ méjì àsopõ

Two consonant and vowel combinations

- Bàbá

-Fìlà

Àkíyèsí

Àwôn õrõ onísílébù púpõ máa þ ní àwôn bátànì ìpilê òkè yìí ní oríÿìíríÿìí õnà.

Father

Cap

Note

Multisyllabic words have these basic patterns above in various combinations.

 

F

Fáwêlì

 

 

 

 

 

 

V

Vowel

 

 

K

Könþsónáýtì

 

C

Consonant

 

 

 

 

 

 

 

Ojú-ìwé Kejìlá

Page 12

 

 

 

 

 

 

 

 

 

ÀTÇ ÀWÒRÁN ÁLÍFÁBËÊTÌ YORÙBÁ

YORÙBÁ ALPHABET PICTORIAL

Àtç àwòrán àwôn õrõ tí ó bêrê tí

Pictorial of words beginning and

ó sì parí pêlú àwôn fáwêlì kannáà

ending with the same vowels

Aa Ee Çç Ii

Oo Ôô Uu

ße àkíyèsí pé àwôn fáwêlì nìkan ni a þ fi àmì ohùn õrõ sí lórí.

Note that intonation marks are placed only on vowels.

Àfikún Álífábëêtì Yorùbá - Yoruba Alphabet Expanded

 

Fáwêli Àìránmúpè

 

 

Oral vowels

 

 

Á á

É é

Ë ë

Í í

Ó ó

Ö ö

Ú ú

A a

E e

Ç ç

I

i

O o

Ô ô

U u

À à

È è

Ê ê

Ì

ì

Ò ò

Õ õ

Ù ù

Fífi ìró ohùn köra lemölemö

Tone Drill

Ó ÿe pàtàkì láti fi kíkö ìró ohùn lemölemö sí ètò êkö akëkõö alákõöbêrê láti ìbêrê. Õrànyàn ni ó jë láti fihàn pé ìro ohùn ÿe góþgó ní sísô èdè Yorùbá. Nýkan tí a þlépa nìyìí nínu apákan ìwé yìí tí ó têlé ojú ìwé yìí.

It is important to incorporate tone drills into the learning process for the beginning student right from the outset. This is necessary to underscore the centrality of tonal sounds in Yoruba discourse. The following section of this book is designed to fulfill this purpose.

Page 13

Ojú-ìwé Kçtàlá

 

 

 

Êkö Kïnní

1

Lesson One

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

P

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

re

 

 

 

 

 

 

 

 

Aa

 

à a á

a-*a

À A Á

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

a- ajá dog

à-ga àga chair

a- apá arm

(re-)

(-re)

(re-)

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

à-gbá

àgbá barrel

a-ta ata pepper

à-

àrá lightning

(-)

 

(re-re)

(-)

 

 

re

Iÿë ÿíÿe

- Exercise

 

 

 

 

 

 

 

 

Read these sentences aloud.

Ka àwôn gbólóhùn õrõ yìí sókè

Mo akan.

Ajá náà ó.

Aòsì mi nìyìí.

I have a dog.

The dog is sitting down. This is my left arm. This is a big oil barrel

Túmõ àwôn õrõ yìí sí Gêësì

Translate these words to English

Àjà, Àgbà Àpá, Àpà Ara, Àrà, A

Page 14

Ojú ìwé kçrìnlá