YorubaPrimer
.pdfÀWÔN BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ
SYLLABLE PATTERNS
Gëgë bí a ti ÿàlàyé tëlê ní ojú-ìwé kçwàá, àwôn bátànì sílébù Yorùbá pín sí oríÿìí mëta báyìí:
As previously explained on page ten, there are three syllable patterns in Yoruba as follows:
1. |
( F ) Fáwêlì |
( V ) Vowel |
2. |
( KF ) Köþþsónáýtì + Fáwêlì (CV) Consonant + Vowel |
|
3. |
(M m, N n) |
Sílébù Àránmúpè (Syllabic Nasal) |
A tún fi yé wa pé ó wúlò láti yára
ÿe àkíyèsí bí ìhun õrõ pêlú sílébù ÿe þÿisë nípa wíwo àwôn õrõ onísílébù méjì díê.
Bátànì méjì sì wáyé -
1. F – KF
a. A - dé b. À - dán
We also noted that it is instructive to quickly note how these syllable building blocks work by illustrating with some bisyllabic words.
Two patterns emerge -
V - CV
ße àkíyèsí pé fáwêlì ìbêrê kò lè jë fáwêlì àránmúpè.
2. KF –KF
a.Bà-bá
b.ßë-gun
c.Sàn-yà
d.Fun-fun
Note that the starting vowel (F, V) cannot be a nasalised vowel.
CV-CV
Ní èdè Gêësì, àwôn fáwèlì méjì péré nínu àlífábëêtì ni o tún lè jë odidi õrõ
tí ó ní ìtumõ. Àwôn ni ‘a’ and ‘ i ’.
Ní èdè Yorùbá, gbogbo àwôn fáwêlì – a, e, ç, i, o, ô, u àti an, çn, in, çn, un ni ó tún lè dá dúró nípò ara wôn gëgë
bí odidi õrõ kan nígbà púpõ.
In the English language, only two vowels in the alphabet can also be a meaningful word. They are the letters ‘a’ and ‘ i ’
(as in A boy, I am here)
In Yoruba, ALL the vowels, both oral and nasalised, may stand alone on their own as distinct words.
|
(Five short of forty) |
Page 35 |
Ojú-ìwé Karùndínlógójì |
Êkö Ogún 20 Lesson Twenty
P
|
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ |
SYLLABLE PATTERNS |
|
|
F, KF |
V, CV |
|
ÀWÔN ÕRÕ ONÍSILÉBÙ KAN |
MONOSYLLABIC WORDS |
Mo bá ç yõ Mo ti dé Mo rí ç Mo bê ö
Má lù mí
Ó dùn mí Mo ti ÿe tán Kí lo wí?
I rejoice with you. I have arrived.
I see you.
I beg you.
Don’t beat me. It hurt me.
I have finished. What did you say?
Iÿë ÿíÿe - Exercise
Kô àwôn õrõ onísílébù kan tìrç síbí.
Write your own list of monosyllabic words here.
|
(Four short of forty) |
Page 36 |
Ojú-ìwé Kçrìndínlógójì |
Êkö Kôkànlélógún 21 Lesson Twenty-One
P
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ |
SYLLABLE PATTERNS |
|
F, KF |
V, CV |
|
ÀWÔN ÕRÕ ONÍSILÉBÙ KAN |
MONOSYLLABIC WORDS |
Parts of the body
O-rí |
Head |
I-mú |
|
Ô-wö |
|
Ç-sê |
|
A-bë |
|
E-yín |
|
Õ-fun |
|
Ô-rùn |
|
I-kùn |
|
O-jú |
Eye |
Ç-nu |
|
Ì-ka |
|
A-pá |
|
Ê-dõ |
|
Ê-yìn |
|
Ô-kàn |
|
À-gbõn |
|
Ì-fun |
|
E-tí |
Ear |
È-tè |
|
Ì-dí |
|
À-yà |
|
A-ra |
|
A-hön |
|
I-tan |
|
I-run |
|
I-ÿan |
|
Iÿë ÿíÿe - Exercise |
(Àyöwí – Wo ojú-ìwé Kôkànlélögöta fún àwôn ìdáhùn díê) |
|
(Hint – see page 61 for some answers) |
|
Kô àwôn êyà ara ní èdè Gêësì
Write the parts of the body in English.
Wo àwôn nöþbà yìí náà. Look at these numbers too.
Ení, Èjì, Êta, Êrin, Àrún, Êfà, Èje, Êjô, Êsán, Êwá
Túmõ àwôn õrõ yìí sí Gêësì
Translate these words to English
Òrí, Ète,Ìkà,Àpá, Àpà, Àgbôn, Agbön, Õkan Ikún, Aya,
|
(Three short of forty) |
Page 37 |
Ojú-ìwé Kçtàdínlógójì |
Êkö Kejìlélógún |
22 Lesson Twenty-Two |
P
ª Ý M N « Þ
Ð ð, Ñ ñ
SYLLABIC NASAL
M, N gëgë bí i sílébù (sílébù àránmúpè)
N yìí yàtõ sí èyí tí ó jë ara õrõ oní sílébù àránmúpè.
m àti n máa þ dún bákan náà
– gëgë bí “ uhn” pêlú ohùn ìsàlê, àárín tàbí òkè tí ó tö sí i.
Ní Yorùbá òde-òní, ìmõràn tí a fi lölê ni pé kí a máa lo m dípò n nígbà tí ó bá wà láàárín õrõ ÿùgbön ogunlögõ òýkõwé ni o ÿì þ lo m nígbà tí ó ba ÿiwájú b pàápàá fún orúkô
Àpççrç
ORÚKÔ NAMES
Abíðbölá - Abí “uhñ” bölá Adéþrelé - Adé “uhþ” relé
ÑÝKAN OBJECT
Òro¸bó - Òro“uhý”bó
Page 38
M, N as a syllable
(syllabic nasal) on its own. This ‘n’ is different from the one that is part of a word with nasalized syllable
m and n sound the same –
like “uhn” with the corresponding low, mid or high pitch.
In modern day Yoruba it has been recommended to replace m with n when it occurs within a word, but many writers still retain its use when it precedes the consonant b, especially in names.
Examples
GBÓLÓHÙN SENTENCE
Mò þ lô |
“uhþ” |
I am going
Kò sí ñýkankan |
“uhñ uhý” |
There is nothing. |
|
Kí lò þ wá? |
“uhþ” |
What are you looking for?
(Two short of forty)
Ojú-ìwé Kejìdínlógójì
Êkö Kçtalélógún |
23 Lesson Twenty-Three |
|
|
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ SYLLABLE PATTERNS
|
F - KF , V -CV |
KF - KF , CV -CV |
|
ÀWÔN ÕRÕ ONÍSILÉBÙ MEJI |
BISYLLABIC WORDS |
A-dé |
Crown |
Ô-lá |
Honour |
Ô-pë |
Thanks |
Ç-wà |
Beauty |
Õ-rë |
Friend |
À-gbê |
Farmer |
I-gba |
Two hundred |
O-kùn |
Rope |
Iÿë ÿíÿe - Exercise
Bà-bá Bà-tà Re-re Dú-dú Kê-kë Jõ-wö ßí-bí ßù-gbön
Father
Shoe
Good
Black
Bicycle
Please
Spoon
But
Kô àwôn õrõ onísílébù méjì tìrç síbí.
Write your own list of bisyllabic words here.
|
(One short of forty) |
Page 39 |
Ojú-ìwé Kôkàndínlógójì |
|
Êkö Kçrìnlélógún 24 |
Lesson Twenty-Four |
|
||||||
|
|
|
|
|
|
|
|||
|
|
|
|
|
|
||||
|
|
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ |
SYLLABLE PATTERNS |
|
|||||
|
|
|
|
KF-KF |
CV-CV |
|
|||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
ÿí-bí ÿíbi spoon |
kê-kë kêkë bicycle |
|
bà-bá bàbá father |
||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
bà-tá bàtà shoe |
fì-là fìlà hat |
gè-lè gèlè head tie |
Iÿë ÿíÿe - Exercise
Kí ni àwôn nýkan wõnyi?
What are these things?
Mo ní kêkë kan |
I have a bicycle |
Bàbá mi ló rà á fún mi. |
My father bought it for me |
Ç ÿeun bàba. |
Thank you dad. |
|
1.**** ni. It is a rope.
2.**** ni.
It is (a box of) eggs.
3**** ni.
It is an orange.
Túmõ àwôn õrõ yìí sí Gêësì.
Translate these words to English.
Bàbà
Bàtá
Òro¸bó
|
(Forty) |
Page 40 |
Ojú-ìwé Ogójì |
|
Êkö Kçêëdögbõn |
25 |
Lesson Twenty-Five |
|||||
P |
|
|
|
|
|
|
|
|
|
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ |
SYLLABLE PATTERNS |
|
|||||
|
|
|
||||||
|
|
KF-KF-KF |
|
CV-CV-CV |
|
|||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
kö-kö-rö kökörö |
ÿò-kò-tò ÿòkòtò |
fè-rè-sé fèrèsé |
key |
pants (trousers) |
window |
ké-ke-ré kékeré
small
pç-lç-bç pçlçbç
flat
pë-pë-yç |
pëpëyç |
ga-ra-wa garawa |
|
duck |
bucket (pail) |
Iÿë ÿíÿe - Exercise
Kí ló wà nínú oko yìí?
What is on this farm?
**** **** ni.
They are three horses.
Ýjë o rí çÿin kçta?
Can you see the third horse?
Page 41
Túmõ àwôn õrõ yìí sí Gêësì.
Translate these words to English.
Roboto
Rçpçtç
(One over forty)
Ojú-ìwé Kôkànlélógójì
Êkö Kçrìndínlögbõn 26 |
Lesson Twenty-Six |
|
|||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ |
SYLLABLE PATTERNS |
|
|
|
|
F-F-KF , V-V-CV |
KF-F-KF , CV-V-CV |
|
|
|
ÀWÔN ÕRÕ ONÍSILÉBÙ MÇTA |
TRISYLLABIC WORDS |
|
|||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
F-F-KF , V-V-CV |
KF-F-KF , CV-V-CV |
a-a-go aago (agogo) clock |
bö-õ-lù böõlù ball |
ká-à-bõ káàbõ welcome
F-F-KF , V-V-CV
o-ò-rùn oòrùn sun
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
KF-KF-F , CV-CV-V |
|
|
|
|
F-KF-KF |
, V-CV-CV |
||
|
bà-lú-ù bàlúù aircraft |
à-gù-tàn àgùtàn sheep |
||
|
|
|
(Two over forty) |
|
Page 42 |
|
Ojú-ìwé Kejìlélógójì |
Êkö Kçtàdínlögbõn |
27 |
|
Lesson Twenty-Seven |
||||||
|
|
|
|
|
|||||
|
ÀWON BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ |
SYLLABLE PATTERNS |
|
||||||
|
|
|
KF-KF-KF-KF |
|
|
CV-CV-CV-CV |
|
||
|
|
|
|
|
|
|
|||
ÀWÔN ÕRÕ ONÍSILÉBÙ MÇRIN |
|
|
WORDS WITH FOUR OR MORE |
||||||
|
TÀBÍ JÙ BËÊ LÔ |
|
|
SYLLABLES |
|||||
|
|
|
KF-KF-KF |
|
|
CV-CV-CV-CV |
|||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
tò-ló-tò-ló |
la-ba-lá-bá |
kë-të-kë-të |
yàn-mù-yán-mú |
|||||
turkey |
|
butterfly |
donkey |
mosquito |
||||
F-KF-KF-KF , V-CV-CV-CV |
|
|
F-KF-F-KF , C-CV-C-CV |
|||||
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
à-lù-bö-sà |
onion |
a-lù-pù-pù motorcycle |
ò-gò-ý-gò ostrich |
|
ÀWON ÕRÕ ONÍSÍLÉBÙ PÚPÕ |
MULTISYLLABIC WORDS |
|||
ADÉBÙSÖLÁ |
(F-KF-KF-KF-KF) The crown has added to our honour |
|||
ÔMÔLÚWÀBÍ |
(F-KF-KF-KF-KF) |
A virtuous child |
|
|
ÔMÔLÚÀBÍ |
(K-KF-KF-F-KF) |
|
|
|
À-LÀ-Á-FÍ-À |
(F-KF-F-KF-F) |
Peace, Health |
|
|
Ô-MÖ-BO-RÍ-O-WÓ (F-KF-KF-KF-F-KF) A child is more important than money |
||||
|
|
|
|
(Three over forty) |
Page 43 |
|
|
|
Ojú-ìwé Kçtàlélógójì |
Ç ç Ô ô ß ÿ
Ó ÿe pàtàkì púpõ láti máa yán àwôn lëtà mëta E, O àti S nídìí pêlú döõtì tàbí ilà olóròó kúkúrú nígbà tí ó bá yç. ßíÿe báyìí ni yóò jë kí òýkàwé tètè mô ìtúmõ tí o tö sí õrõ náà.
Àti döõtì àti ilà olóròó kúkúrú ni àkôtö èdè Yorùbá fôwö sí. Fífa ilà gbôôrô çlëbùú sábë àwôn lëtà yìí lòdì sí òfin akôtö.
Lílo ilà olóròó kúkúrú ni mo fëràn jù ní tèmi nítorí pé:
Ó bójú mu ní wíwò lójú ìwé Kì í parë tí a bá fa ilà sábë õrõ.
Wo àwôn àpççrç ìsàlêyìí
It is very important to insert a dot or short vertical bar under the three letters E, O and S in a word whenever necessary. In doing this, the correct meaning of the word can be quickly known by the reader.
Both the dot and short vertical bar are approved in Yoruba orthography. Using a dash under these letters is against orthographic convention.
My preferred method is the short vertical bar because:
It is aesthetically pleasing on the page It is not occluded when words are underlined.
Look at the examples below.
Êê |
Çç |
Ëë |
Õõ |
Ôô |
Öö |
ßÿ |
Êê |
Çç |
Ëë |
Õõ |
Ôô |
Öö |
ßÿ |
A rí ilà tí a fà gedegbe lábë ilà olóròó kúkúrú náà. Kò pa á rë.
The line can be seen distinctly below the short vertical bar. It has not obstructed it.
|
Ẹ̀ |
ẹ̀Ẹ ẹ Ẹ́ |
Òẹ́ọ̀ |
Ọ́Ọ ọọ́Ṣ |
ṣ |
|
|
Ẹ̀ |
ẹ̀Ẹ ẹ Ẹ́ |
Òẹ́ọ̀ |
Ọ́Ọ ọọ́Ṣ |
ṣ |
|
Ilà tí a fà ti pa döõtì rë. |
The dot is cut off by the line |
|
(Four over forty) |
Page 44 |
Ojú-ìwé Kçrìnlélógójì |