YorubaPrimer
.pdfÊkö Kejìdínlögbõn 28 Lesson Twenty-Eight
|
Èè |
Ee Éé |
Êê |
Çç Ëë |
|
|
|
|
|
|
|
|
è |
e é |
ê |
ç ë |
|
Èdè |
|
Çdç (a town in Yoruba land) |
|||
Yorùbá ni èdè mi. |
|
Çdç ni ìlú mi. |
|||
Yoruba is my language. |
|
Çdç is my home-town. |
|||
Ètè |
|
Êtê |
|
|
|
Ètè mi wú |
|
Àìsàn ni êtê |
|||
My lip is swollen |
|
Leprosy is a disease |
Erin
Çranko þlá ni erin
The elephant is a big animal.
Êrín
Êrín yìí põjù
This laughter is too much.
Ejò |
Çjö |
Ejò olóró ni. |
Çjö mi ni |
It is a poisnous snake. |
It is my fault |
Èso |
Êsö |
Eso yìí dùn púpõ |
Iÿë yìí gba êsõ. |
This fruit is very sweet. |
This work requires carefulness. |
Ebè |
Êbê |
Àgbê ti kô ebè láti gbin iÿu. |
Êbê ni mo bç ö. |
The farmer has prepared the heap |
I am begging you. |
of earth for planting yams. |
|
Wo ìyàtõ láàárín E e àti Ç ç
Observe the difference between E e and Ç ç
|
(Five short of fifty) |
Page 45 |
Ojú-ìwé Karùndínláàádöta |
Êkö Kôkàndínlögbõn 29 Lesson Twenty-Nine
|
Ò |
O Ó |
Õ |
Ô |
Ö |
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
ò |
o ó |
õ |
ô |
ö |
|
|
|
|
|
|
|
|||
Owó |
Money |
|
Ôwö |
Hand |
Owó wà ní ôwö mi.
There is money in my hand.
Òjò |
Rain |
Òjò |
þ rõ. |
It is raining.
Oyún Pregnancy
Oyún kejì nìyìí.
This is the second pregnancy.
Oko Farm
Oko Àdùkë nìyìí.
This Aduke’s farm.
Olè Thief
Ôjö |
Day |
Ôjö |
wo nìyìí? |
What day is this?
Ôyún Pus
Ôyún wà lójú egbò yìí.
There is pus on this sore.
Ôkô Husband
Ôkô Àdùkë nìyìí
This is Aduke’s husband.
Õlç |
Lazy (person) |
|
|
Õlç ni ó þ di olè.
A lazy (person) becomes a thief.
|
Kòkòrò |
Insect |
|
|
Kökörö |
Key |
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
Wo ìyàtõ láàárín O o àti Ô ô |
||||
|
|
Observe the difference between O o and Ô ô |
|||||
|
|
|
|
|
|
(Four short of fifty) |
|
Page 46 |
|
|
|
|
Ojú-ìwé Kçrìndínláàádöta |
Êkö Ôgbõn |
30 |
Lesson Thirty |
|
|
|
S s ß ÿ
Çsê Leg
Çsê þ dún mí.
My leg is hurting.
Õsê Week
Õsê kan kò tó.
One week is not enough.
Asõ Quarrel
Asõ kò dára.
Quarelling is not good.
Òsì left
Ôwö òsì mi niyìí.
This is my left hand.
Àsè feast
Àsè ìgbéyàwó ni.
It is a wedding feast.
Êÿê Sin
Êÿê ni irö pípa.
Telling lies is a sin.
Ôÿç Soap
Ôÿç yìí dára.
This soap is good.
Aÿô Cloth
Aÿô yìí dára
This cloth is good
Òÿì poverty
Kò sí òÿì níbí.
There is no poverty here.
Àÿç
Àÿç ni.
It is an order.
|
Wo ìyàtõ láàárín S s àti ß ÿ |
|
Observe the difference between S s and ß ÿ |
|
(Three short of fifty) |
Page 47 |
Ojú-ìwé Kçtàdínláàádöta |
Àkàyé
Comprehension
Nísisiyìí, àsìkò wá tó láti lo àwôn êkö tí ç ti kö nínú ìwé yìí láti ìbêrê ní àwôn ojù-ìwé tí ó têlé èyìí.
A óò ÿe àyêwò àwôn àpólà, gbólóhùn õrõ àti ìkíni Yorubá. A óò pàdé çbí Ômôlúwàbí, a óò sì kö nípa Bíÿöõbù Sámúëlì Àjàyí Crowther àti ìtàn iÿêdálê ìjôba ìlê Yourùbá.
Iÿë yá.
It is now time to put into practice what you have learnt in this book so far in the following pages.
We shall examine phrases, sentences,
Yoruba greetings, meet the Omoluwabi family and learn about Bishop Samuel Ajayi Crowther and some basic history of the Yoruba kingdom.
Get ready to work.
Ka àwôn gbólóhùn tí a kô sílê lësççsç.
Read the sentences written down systematically.
|
(Two short of fifty) |
Page 48 |
Ojú-ìwé Kejìdínláàádöta |
ÌKÍNI GREETINGS
P
Ìkíni ní oríÿìíríÿìí ìgbà àti fún oríÿìíríÿìí ìÿêlê wöpõ ní àÿà Yorùbá. Díê nínú wôn nìyìí.
Çkáàárõ
Çkáàsàn
Çkúrõlë
Çkáalë Ó dàárõ Ó dàbõ
Çkáàbõ
Çkúulé
Çkú àtijö
Çkú ôjö mëta
ßé àlàáfíà ni?
Çkú ìnáwó
Çkú ìdìde
Çkú àfojúbà
Çkú ìgbádùn
Page 49
Greetings at various times for various occasions are very common in Yoruba culture. Here are some of them.
Good morning. Good afternoon. Good evening.(early) Good evening. (late)
Good night (till morning). Good bye.
Welcome.
Greetings on meeting you at home. Quite an age.
Have not seen you in a while.
How are you? (are you in good health?
Greetings for spending money. Greetings for coming. Greetings for seeing a visitor. Greetings for enjoying yourself.
(One short of fifty)
Ojú-ìwé Kôkàndínláàádöta
P |
ÌKÍNI |
GREETINGS |
|
|
|
|
|
|
|
|
Õrõ àti èsì |
|
Conversation |
|
Ì - Ìbéèrè |
Q - Question |
È - Èsì |
A - Answer |
ÌÇ káàárõ o, Màmá Bísí
ÈO o, káàárõ o.
Ìße dáadáa ni?
ÈA dúpë
ÌÀwôn ômô þkö?
ÈWön wà ní àlàáfíà
ÌBaálé þkö?
ÈÀlàáfíà
ÌNíbo ni ê þlô?
ÈMò þlô söjà. Ó dàbõ o.
O o, ó dàbö
Q |
Good morning, |
Bisi’s mother. |
|
||
A |
Yes, good morning. |
|
|
||
Q |
How are you? |
(Is it well with you?) |
|
A |
Thank you. |
|
|
Q |
How are the children |
|
|
A |
They are in good health. |
|
|
Q |
How is your husband ? |
|
|
A |
Fine. |
|
|
Q |
Where are you going? |
|
AI am going to the market. Good bye.
Yes, good bye
|
(Fifty) |
Page 50 |
Ojú-ìwé Àádöta |
Çbí Ômôlúwàbí
The Omoluwabi Family
Õgbëni Akíntúndé Àkànbí |
|
Abilékô Ômôlará Àdùkë |
Ômôlúwàbí |
|
Ômôlúwàbí |
Mr. Akintunde Akanbi Omoluwabi |
|
Mrs. Omolara Aduke Omoluwabi |
|
|
|
Miss |
|
Miss |
|
Master |
Ôláþrewájú |
|
Olúwafúnmiláyõ |
|
Adéôlá |
Ômöboöláþlé |
|
Olúwaÿeun |
|
Adéyçmí |
Ôlá |
|
Olú |
|
Adé |
|
|
|
|
|
Àköbí - First born child |
|
Àbíkëhìn - Last born child |
Obìnrin - Female |
Obìnrin - Female |
Ôkùnrin - Male |
|
(One over fifty) |
Page 51 |
Ojú-ìwé Kôkànléláàádöta |
P
Çbí Ômölúwàbí jókòó láti jç oúnjç àárõ
The Omoluwabi family at breakfast
Çbí Ômôlúwàbí jókòó láti jç oúnjç àárõ. Búrëdì àti çyin díndín ni wön fëë jç, ÿùgbön iÿu àti õgêdê sísè ni bàbá yóò jç ní tire.
Ìyá ti po tíì fún àwôn ômô, kôfí sì ni òun àti bàba yóò mu ní tiwôn.
Kò yá àwôn ômô lára láti jòkòó báyìí. Wôn féë lô sí Makidónálìdì láti lo jç bögà àti fráìsì ni.
The Omoluwabi family is sitting down to eat breakfast. They are going to eat bread and fried eggs but Dad will be eating yam and boiled plantain by himself.
Mom had prepared tea for the children. She and Dad will be drinking coffee.
One of the kids has spilled milk on the table. Mom is finding out who did it.
The kids are not too excited sitting down like this. They prefer to go to McDonalds to
eat burger and fries.
|
(Two over fifty) |
Page 52 |
Ojú-ìwé Kejìléláàádöta |
P |
Çbí Ômôlúwàbí þ jç oúnjç àárõ |
|
The Omoluwabi family at breakfast |
Bàbà gbádùn oúnjç tí a fi töô dàgbà. Kò fëë gbàgbé ìgbà èwe rê. Ojoojúmö ni ó máa þ sô fún àwôn ômô pé: Bögà láàárõ, Bögà lösàn-àn, Bögà lálë
– ó màÿe o!
Page 53
Dad likes the types of food he was brought up with. He does not want to forget his youth. He says to the kids everyday - Burger in the morning, burger in the afternoon, burger at night.What a pity !
(Three over fifty)
Ojú-ìwé Kçtàléláàádöta
Abilékô Ômôlúwàbí |
|
Mrs Omoluwabi |
(Màmá Ôlá) |
|
(Ola’s mother) |
|
|
|
Ômôlará ni orúkô rê. Ó tún þ jë Àdùkë. Oríkì ni orúkô kejì yìí. Ômô ôdún mëêëdögbõn ni. Bàbá Ôlá ni àwôn çgbë rê þ pè e gëgë bí àÿà ìbílê nítorí pé Ôlá ni àköbí àwôn ômô rê.
Màmá Ôlá þ se oúnjç. Oúnjç õsán nìyìí. Êbà ni ó þ rò. Omi gbígbóná ni ó fi þ tç gaàrí tí yóò di êbà yìí.
Ó ti se ôbê êfö sílê. Ó fi çja àti oríÿìíríÿìí çran síi. Àwôn ômô gbádùn oúnjç yìí ÿùgbön bí a bá bi wôn léèrè pé èwo ni ó dára jù nínú êbà àti bögà, wön á pariwo gèèè… wön á ní bögàààà…bögàààa…
Bàbá yóò tún wipe Bögà láàárõ, Bögà lösàn-àn, Bögà lálë - ó màÿe o!
Page 54
Her name is Omolara. She also bears the name Aduke. This second name is a cognomen. She is thirty-five years old. His mates call him Baba Ola as is the cultural practice because Ola is his first born child.
Ola’s mother is preparing a meal. This is lunch.
She is preparing eba
She is mixing gaari in hot water then it becomes eba.
She had cooked the vegetable stew earlier. She put fish and assorted meat in it. The kids love this food, but if they are asked which one is better - eba or burgerthey’ll shout gleefully ... and say burgerr...
burgerr...
Dad will say again Burger in the morning, burger in the afternoon, burger at night - what a pity !
(Four over fifty)
Ojú-ìwé Kçrìnléláàádöta